Micah 5:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
O óo lágbára ju àwọn ọ̀tá rẹ lọ, a óo sì pa wọ́n run.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
A o gbe ọwọ́ rẹ soke sori awọn ọ̀ta rẹ, gbogbo awọn ọ̀ta rẹ, li a o si ke kuro.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
A ó gbé ọwọ́ rẹ̀ sókè ní ìṣẹ́gun lórí àwọn ọ̀tá rẹ̀, gbogbo àwọn ọ̀ta rẹ̀ sì ni a ó parun.