Micah 6:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Báwo ni mo ṣe lè dáríjì àwọn tí ń lo òṣùnwọ̀n èké; tí àpò wọn sì kún fún ìwọ̀n tí kò péye?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki emi ha kà wọn si mimọ́ pẹlu òṣuwọ̀n buburu, ati pẹlu àpo òṣuwọ̀n ẹ̀tan?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ǹjẹ́ èmi ha lè kà wọ́n sí mímọ́ pẹ̀lú òṣùwọ̀n búrurú, pẹ̀lú àpò òṣùwọ̀n ẹ̀tàn?