Micah 6:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Èmi ni mo sá mu yín jáde láti ilẹ̀ Ijipti, tí mo rà yín pada kúrò lóko ẹrú; tí mo rán Mose, Aaroni ati Miriamu láti ṣáájú yín.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori mo ti mu ọ goke lati ilẹ Egipti wá, mo si rà ọ padà lati ile ẹrú wá; mo si rán Mose, Aaroni, ati Miriamu siwaju rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí èmi mú un yín gòkè láti ilẹ̀ Éjíbítì wá, mo sì rà yín padà láti ilẹ̀ ẹrú wá. Mo rán Mósè láti darí yín bákan náà mo rán Árónì àti Míríámù ṣíwájú rẹ̀.