Micah 7:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn ayé yóo di ahoro nítorí ìwàkiwà àwọn tí wọn ń gbé inú rẹ̀; àní nítorí iṣẹ́kíṣẹ́ ọwọ́ wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ilẹ na yio si di ahoro fun awọn ti ngbe inu rẹ̀, nitori eso ìwa wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ilẹ̀ náà yóò di ahoro fún àwọn olùgbé ìnú rẹ̀, nítorí èso ìwà wọn.