Micah 7:2 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Olóòótọ́ ti tán lórí ilẹ̀ ayé, kò sí olódodo mọ́ láàrin àwọn eniyan; gbogbo wọn ń wá ọ̀nà ìpànìyàn, olukuluku ń fi àwọ̀n dọdẹ arakunrin rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oninurere ti run kuro li aiye: kò si si olotitọ kan ninu enia: gbogbo wọn ba fun ẹ̀jẹ, olukuluku wọn nfi àwọn dẹ arakunrin rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn olódodo sì ti kúrò ní ilẹ̀ náà, kò sì sí ẹnìkan tí ó ṣẹ́kù tí ó jọ olóòótọ́; gbogbo wọn sì ń purọ́ ní dídúró nítorí ìtàjẹ̀sílẹ̀, olúkúlùkù wọ́n sì ń fi àwọ̀n de arákùnrin rẹ̀.