Nahum 2:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Níbo ni ìlú tí ó dàbí ihò àwọn kinniun wà? Tí ó rí bí ibùgbé àwọn ọ̀dọ́ kinniun? Ibi tí kinniun ń gbé oúnjẹ rẹ̀ lọ, tí àwọn ọmọ rẹ̀ wà, tí kò sí ẹni tí ó lè dà wọ́n láàmú?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nibo ni ibugbé awọn kiniun wà, ati ibujẹ awọn ọmọ kiniun, nibiti kiniun, ani agbà kiniun, ti nrìn, ati ọmọ kiniun, kò si si ẹniti o dẹruba wọn?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Níbo ni ihò àwọn kìnnìún wà àti ibi ìjẹun àwọn ọmọ kìnnìún, níbi tí kìnnìún, àní abo kìnnìún ti ń rìn, àti ọmọ kìnnìún, láìsí ohun ìbẹ̀rù