Nahum 3:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wò ó! Àwọn ọmọ ogun rẹ dàbí obinrin! Gbogbo ẹnubodè rẹ wà ní ṣíṣí sílẹ̀ fún àwọn ọ̀tá rẹ; iná sì ti jó gbogbo ọ̀pá ìdábùú ìlẹ̀kùn bodè rẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Kiye si i, obinrin li awọn enia rẹ lãrin rẹ: oju ibodè ilẹ rẹ li a o ṣi silẹ gbaguda fun awọn ọta rẹ: iná yio jo ikere rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kíyè sí, Obínrin ni àwọn ènìyàn rẹ ní àárin! Ojú ibodè rẹ ní a ó sí sílẹ̀ gbagada, fún àwọn ọ̀tá rẹ̀; iná yóò jó ilẹ̀ rẹ