Nahum 3:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
O ti wá kún àwọn oníṣòwò rẹ, wọ́n sì pọ̀ ju ìràwọ̀ ojú ọ̀run lọ! Ṣugbọn wọ́n ti na ìyẹ́ wọn bí eṣú, wọ́n sì fò lọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ ti sọ awọn oniṣòwo rẹ di pupọ̀ jù iràwọ oju ọrun lọ: kokòro nà ara rẹ̀, o si fò lọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìwọ ti sọ àwọn oníṣòwò rẹ di púpọ̀ títí wọn yóò ṣe pọ̀ ju ìràwọ̀ oju ọ̀run lọ Kòkòrò na ara rẹ̀ ó sì fò lọ.