Nehemiah 10:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn tí wọ́n fi ọwọ́ sí ìwé náà tí wọ́n sì fi èdìdì dì í nìwọ̀nyí: Nehemaya, gomina, ọmọ Hakalaya, ati Sedekaya.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
AWỌN ti o fi èdidi di i ni Nehemiah, bãlẹ, ọmọ Hakaliah, ati Sidkijah.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn tí ó fi èdìdì dìí ni: Nehemáyà baálẹ̀, ọmọ Hakaláyà. Ṣedekáyà