Nehemiah 10:14 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ìjòyè wọn tí wọ́n fọwọ́ sí ìwé náà ni: Paroṣi, Pahati Moabu, Elamu, Satu, ati Bani,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn olori awọn enia; Paroṣi, Pahati-moabu, Elamu, Sattu, Bani.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn olórí àwọn ènìyàn: Párósì, Páhátí-Móábù, Élámù, Ṣátù, Bánì,