Nehemiah 10:9 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Lẹ́yìn náà àwọn ọmọ Lefi wọnyi: Jeṣua ọmọ Asanaya, Binui ọ̀kan ninu àwọn ọmọ Henadadi, ati Kadimieli,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati awọn ọmọ Lefi: ati Jeṣua ọmọ Asaniah, Binnui, ọkan ninu awọn ọmọ Henadadi, Kadmieli;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ Léfì: Jéṣúà ọmọ Aṣanáyà, Bínúyì ọ̀kan nínú àwọn ọmọ Hénédédì, Kádímélì,