Nehemiah 11:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn eniyan náà súre fún àwọn tí wọ́n fa ara wọn kalẹ̀ láti lọ máa gbé Jerusalẹmu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn enia si sure fun gbogbo awọn ọkunrin na ti nwọn yan ara wọn lati gbe Jerusalemu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ènìyàn súre fún gbogbo àwọn ọkùnrin tí wọ́n jọ̀wọ́ ara wọn láti gbé ní Jérúsálẹ́mù.