Nehemiah 12:1 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Orúkọ àwọn alufaa ati àwọn ọmọ Lefi tí wọ́n bá Serubabeli ọmọ Ṣealitieli ati Jeṣua dé nìwọ̀nyí: Seraaya, Jeremaya ati Ẹsira,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
WỌNYI si ni awọn alufa ati awọn ọmọ Lefi ti o ba Serubbabeli ọmọ Ṣealtieli goke lọ, ati Jeṣua: Seraiah Jeremiah, Esra,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn wọ̀nyí ni àwọn àlùfáà àti àwọn ọmọ Léfì tí ó bá Ṣérúbábélì ọmọ Ṣéálítíélì àti Jéṣúà padà: Ṣeraiáyà, Jeremáyà, Éṣírà,