Nehemiah 12:23 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àkọsílẹ̀ orúkọ àwọn baálé baálé ninu àwọn ọmọ Lefi títí di ìgbà ayé Johanani ọmọ Eliaṣibu wà ninu ìwé Kronika.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ Lefi, olori awọn baba li a kọ sinu iwe itan titi di ọjọ Johanani ọmọ Eliaṣibu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn olórí ìdílé láàrin àwọn ọmọ Léfì títí di àkókò Jóhánánì ọmọ Élíáṣíbù ni a kọ sílẹ̀ nínú ìwé ìtàn.