Nehemiah 13:23 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà náà, mo rí àwọn Juu tí wọn fẹ́ iyawo lára àwọn ará Aṣidodu, àwọn ará Amoni ati ti Moabu,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Pẹlupẹlu li ọjọ wọnni, mo ri ara Juda ti mba obinrin awọn ara Aṣdodi, Ammoni, ati ti Moabu gbe:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní ọjọ́ wọ̀n ọn nì, mo rí àwọn ọkùnrin Júdà tí wọ́n fẹ́ àwọn obìnrin láti Áṣídódù, Ámónì àti Móábù.