Nehemiah 2:10 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn nígbà tí Sanbalati ará Horoni ati Tobaya iranṣẹ ọba, ará Amoni gbọ́, inú bí wọn pé ẹnìkan lè máa wá alaafia àwọn ọmọ Israẹli.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati Sanballati ara Horoni ati Tobiah iranṣẹ ara Ammoni gbọ́, o bi wọn ni inu gidigidi pe, enia kan wá lati wá ire awọn ọmọ Israeli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí Ṣáńbálátì ará Hórónì àti Tòbáyà ará a Ámónì tí wọ́n jẹ́ ìjòyè gbọ́ nípa èyí pé, ẹnikan wá láti mú ìtẹ̀ṣíwájú bá àlàáfíà àwọn ará Ísírẹ́lì inú bí wọn gidigidi.