Nehemiah 2:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Mo fún ọba lésì pé, “Bí ó bá tẹ́ kabiyesi lọ́rùn bẹ́ẹ̀, kí kabiyesi kọ̀wé lé mi lọ́wọ́ kí n lọ fún àwọn gomina ìgbèríko òdìkejì odò, kí wọ́n lè jẹ́ kí n rékọjá lọ sí Juda,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Pẹlupẹlu mo wi fun ọba pe, bi o ba wù ọba, ki o fun mi ni iwe si awọn bãlẹ li oke odò, ki nwọn le mu mi kọja titi emi o fi de Juda;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mo sì tún wí fún-un pé, “Tí ó bá wu ọba, kí ó fún mi ní lẹ́tà sí àwọn baálé agbégbé Éúfúrétè nítorí kí wọ́n báà lè jẹ́ kí n la ọ̀dọ̀ wọn kọjá lọ sí Júdà láìléwu