Nehemiah 4:10 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ará Juda bẹ̀rẹ̀ sí kọrin pé, “Agbára àwa tí à ń ṣe iṣẹ́ ń dín kù, iṣẹ́ sì tún pọ̀ nílẹ̀; ǹjẹ́ a ó lè mọ odi náà mọ́ báyìí?”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Juda si wipe, Agbara awọn ti nru ẹrù dínkù, àlapa pupọ li o wà, tobẹ̃ ti awa kò fi le mọ odi na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lákòókò yìí, àwọn ènìyàn Júdà wí pé, “Agbára àwọn òṣìṣẹ́ ti dínkù, àlàpà púpọ̀ ni ó wà tó bẹ́ẹ̀ tí àwa kò fi le è mọ odi náà.”