Nehemiah 7:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Pahati Moabu, tí wọ́n jẹ́ ọmọ Jeṣua ati Joabu, jẹ́ ẹgbẹrinla ó lé mejidinlogun (2,818).
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ Pahat-moabu, ti awọn ọmọ Jeṣua, ati Joabu, ẹgbẹrinla o le mejidilogun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
ti Páhátì—Móábù (láti ipaṣẹ̀ ìran Jéṣúà àti Jóábù) ẹgbàá mẹ́rìnlá ó lé méjìdínlógún — (2,818) —