Nehemiah 7:39 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn alufaa nìwọ̀nyí: àwọn ọmọ Jedaaya, tí wọ́n jẹ́ ti ìdílé Jeṣua, jẹ́ ẹẹdẹgbẹrun ó lé mẹtalelaadọrin (973).
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn alufa: awọn ọmọ Jedaiah ti ile Jeṣua, ẹgbã o di mẹtadilọgbọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn Àlùfáà: — àwọn ìran Jédáyà (láti ipaṣẹ̀ ìdílé Jéṣúà) ẹgbàá ó dín mẹ́tadínlọ́gbọ̀n — (973) —