Nehemiah 7:43 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Lefi nìwọ̀nyí: àwọn ọmọ Jeṣua, tí wọn ń jẹ́ Kadimieli, ní ìdílé Hodefa, jẹ́ mẹrinlelaadọrin.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ Lefi: awọn ọmọ Jeṣua, ti Kadmieli, ninu ọmọ Hodafa, mẹrinlelãdọrin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn Ìran Léfì: — àwọn ìran Jéṣúà (láti ipaṣẹ̀ Kádímélì, láti ipaṣẹ̀ Hódáfíà) mẹ́rìnléláàdọ́rin — (74)