Nehemiah 7:45 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn olùṣọ́ ẹnubodè nìwọ̀nyí: àwọn ọmọ Ṣalumu, àwọn ọmọ Ateri, àwọn ọmọ Talimoni, àwọn ọmọ Akubu, àwọn ọmọ Hatita, ati àwọn ọmọ Ṣobai. Gbogbo wọn jẹ́ mejidinlogoje (138).
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn oludena: awọn ọmọ Ṣallumu, awọn ọmọ Ateri, awọn ọmọ Talmoni, awọn ọmọ Akkubu, awọn ọmọ Hatita, awọn ọmọ Ṣobai, mejidilogoje.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn Aṣọ́bodè: — àwọn ìran — Ṣílámù, Átérì, Támónì, Ákúbù, Hátítà, àti Ṣóbáì, méjìdínlógóje — (138)