Nehemiah 7:60 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Gbogbo àwọn tí wọn ń ṣe iṣẹ́ iranṣẹ ninu tẹmpili ati àwọn ọmọ àwọn iranṣẹ Solomoni jẹ́ irinwo ó dín mẹjọ (392).
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gbogbo awọn Netinimu, ati awọn ọmọ awọn iranṣẹ Solomoni jẹ irinwo din mẹjọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ìránṣẹ́ ilé tẹ́ḿpìlì àti àwọn ìran ìránṣẹ́ Sólómónì jẹ́ irinwó dín mẹ́jọ — (392)