Nehemiah 7:62 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
àwọn ọmọ Delaaya, àwọn ọmọ Tobaya, ati àwọn ọmọ Nekoda. Wọ́n jẹ́ ojilelẹgbẹta ó lé meji (642).
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ Delaiah, awọn ọmọ Tobiah, awọn ọmọ Nekoda, ojilelẹgbẹta ole meji.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ìran — Déláyà, Tóbíyà àti Nékódà, jẹ́ òjìlélẹ́gbẹ̀ta ó lé méjì — (642)