Nehemiah 7:65 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Gomina sọ fún wọn pé wọn kò gbọdọ̀ fẹnu kan oúnjẹ mímọ́ jùlọ títí tí alufaa kan tí ó lè lo Urimu ati Tumimu yóo fi dé.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bãlẹ na si wi fun wọn pe, ki nwọn máṣe jẹ ninu ohun mimọ́ julọ, titi alufa kan yio fi duro pẹlu Urimu, ati Tummimu,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Baálẹ̀, sọ fún wọn nítorí náà pé wọn kò gbọdọ̀ kópa nínú un jíjẹ oúnjẹ mímọ́ títí tí àlùfáà tí yóò wá tí ń ṣiṣẹ́ ìránṣẹ́ pẹ̀lúu Úrímù àti Tímímù yóò fi dé.