Nehemiah 7:66 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Gbogbo àwọn tí wọ́n wà ní àpéjọpọ̀ náà jẹ́ ọ̀kẹ́ meji ati ẹgbaa ó lé ojidinnirinwo (42,360),
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iye gbogbo ijọ jasi ẹgbãmọkanlelogun o le ojidinirinwo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo ìjọ ènìyàn tí wọ́n péjọ pọ̀ jẹ́ ẹgbàámọ́kànlélógún ó lé òjìdínnírinwó (42,360)