Numbers 1:10 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ninu àwọn ọmọ Josẹfu, Eliṣama ọmọ Amihudu ni yóo jẹ́ olórí láti inú ẹ̀yà Efuraimu; Gamalieli ọmọ Pedasuri ni yóo sì jẹ́ olórí láti inú ẹ̀yà Manase.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ti awọn ọmọ Josefu: ti Efraimu; Elliṣama ọmọ Ammihudu: ti Manasse; Gamalieli ọmọ Pedasuru.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Láti ọ̀dọ̀ àwọn sọmọ Jósẹ́fù: láti ọ̀dọ̀ Éfraimù, Elisámà ọmọ Ámíhúdì; Láti ọ̀dọ̀ Mánásè, Gámáélì ọmọ Pedasúrù;