Numbers 1:23 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
jẹ́ ẹgbaa mọkandinlọgbọn ó lé eedegbeje (59,300).
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ti a kà ninu wọn, ninu ẹ̀ya Simeoni, o jẹ́ ẹgba mọkandilọgbọ̀n o le ẹdegbeje.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Iye àwọn tí á kà nínú ẹ̀ya Símónì jẹ́ ẹgbàá mọ́kàndínlógún-ó-lé ọ̀ọ́dúnrún (59,300).