Numbers 1:25 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
jẹ́ ẹgbaa mejilelogun ó lé aadọta lé ní ẹgbẹjọ (45,650).
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ti a kà ninu wọn, ninu ẹ̀ya Gadi, o jẹ́ ẹgba mejilelogun o le ãdọtalelẹgbẹjọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Iye àwọn tí a kà nínú ẹ̀yà Gáádì jẹ́ ẹgbàá-ó-lé-àádọ́ta-lé-lẹ́gbẹ̀jọ (45,650).