Numbers 1:27 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
jẹ́ ẹgbaa mẹtadinlogoji ó lé ẹgbẹta (74,600).
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ti a kà ninu wọn, ninu ẹ̀ya Juda, o jẹ́ ẹgbã mẹtadilogoji o le ẹgbẹ̀ta.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Iye tí a kà nínú ẹ̀yà Júdà jẹ́ ẹgbàá mẹ́tadínlógójì-ó-lé-ẹgbẹ́ta (74,600).