Numbers 1:29 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
jẹ́ ẹgbaa mẹtadinlọgbọn ó lé irinwo (54,400).
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ti a kà ninu wọn, ninu ẹ̀ya Issakari, o jẹ́ ẹgbã mẹtadilọgbọ̀n o le irinwo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Iye tí a kà nínú ẹ̀yà Íṣákárì jẹ́ ẹgbàá mẹ́tadínlógójì-ó-lé-irinwó (54,400).