Numbers 1:33 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
jẹ́ ọ̀kẹ́ meji ó lé ẹẹdẹgbẹta (40,500).
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ti a kà ninu wọn, ninu ẹ̀ya Efraimu, o jẹ́ ọkẹ meji o le ẹdẹgbẹta.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Iye tí a kà nínú ẹ̀yà Éfúráímù jẹ́ ọ̀kẹ́ méjì-ó-lé-ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta (40,500).