Numbers 1:41 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
jẹ́ ọ̀kẹ́ meji le ẹẹdẹgbẹjọ (41,500).
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ti a kà ninu wọn, ninu ẹ̀ya Aṣeri, o jẹ́ ọkẹ meji o le ẹdẹgbẹjọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Iye tí a kà nínú ẹ̀yà Áṣérì jẹ́ ọ̀kẹ́ méjì-ó-lé-ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀jọ (41,500).