Numbers 1:47 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣugbọn wọn kò ka àwọn ọmọ Lefi mọ́ wọn,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn awọn ọmọ Lefi gẹgẹ bi ẹ̀ya baba wọn li a kò kà mọ́ wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
A kò ka àwọn ìdílé ẹ̀yà Léfì mọ́ àwọn ìyókù.