Numbers 10:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn alufaa, ọmọ Aaroni ni yóo máa fọn fèrè náà. “Fèrè yìí yóo sì jẹ́ ìlànà fún ìrandíran yín.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ Aaroni, awọn alufa, ni ki o si fun ipè na; ki nwọn ki o si ma ṣe ìlana lailai fun nyin ni iran-iran nyin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Àwọn Ọmọ Árónì tí í ṣe àlùfáà ni kí ó máa fun fèrè. Èyí yóò jẹ́ ìlànà láéláé fún yín àti fún ìran tó ń bọ̀.