Numbers 11:14 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Èmi nìkan kò lè ṣe àkóso àwọn eniyan wọnyi; ẹrù náà wúwo jù fún mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi nikan kò le rù gbogbo awọn enia yi, nitoriti nwọn wuwo jù fun mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi nìkan kò lè dá gbé wàhálà àwọn ènìyàn wọ̀nyí, ẹrù wọn ti wúwo jù fún mi.