Numbers 11:30 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Lẹ́yìn náà Mose ati àwọn aadọrin olórí náà pada sí ibùdó.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Mose si lọ si ibudó, on ati awọn àgba Israeli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mósè àti àwọn àgbààgbà yìí sì padà sínú àgọ́.