Numbers 11:35 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn eniyan náà sì ṣí kúrò níbẹ̀ lọ sí Haserotu, wọ́n sì pàgọ́ wọn sibẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn enia na si dide ìrin wọn lati Kibrotu-hattaafa lọ si Haserotu; nwọn si dó si Haserotu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ènìyàn yóòkù sì gbéra láti Kíbírótì Hátafà lọ pa ibùdó sí Hásérótì wọ́n sì dúró nibẹ̀.