Numbers 13:25 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Lẹ́yìn tí wọ́n ti wo ilẹ̀ náà fún ogoji ọjọ́, àwọn amí náà pada.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn si pada ni rirìn ilẹ na wò lẹhin ogoji ọjọ́.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n padà sílé lẹ́yìn ogójì ọjọ́ tí wọ́n ti lọ yẹ ilẹ̀ náà wò.