Numbers 13:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Mose bá rán àwọn ọkunrin tí wọ́n jẹ́ olórí ninu ẹ̀yà wọn lọ, láti aṣálẹ̀ Parani.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Mose si rán wọn lati ijù Parani lọ, gẹgẹ bi aṣẹ OLUWA: gbogbo awọn ọkunrin na jẹ́ olori awọn ọmọ Israeli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mósè sì rán wọn jáde láti Aginjù Páránì gẹ́gẹ́ bí àṣẹ OLÚWA. Gbogbo wọn jẹ́ olórí àwọn ènìyàn Ísírẹ́lì.