Numbers 13:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Orúkọ wọn nìwọ̀nyí: láti inú ẹ̀yà Reubẹni, ó rán Ṣamua ọmọ Sakuri;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Orukọ wọn si ni wọnyi: ninu ẹ̀ya Reubeni, Ṣammua ọmọ Sakuru.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Orúkọ wọn nìwọ̀nyí: láti inú ẹ̀yà Rúbẹ́nì Ṣámuá ọmọ Ṣákúrì;