Numbers 13:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
láti inú ẹ̀yà Isakari, ó rán Igali, ọmọ Josẹfu;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ninu ẹ̀ya Issakari, Igali ọmọ Josefu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Láti inú ẹ̀yà Ísíkárì, Ígálì ọmọ Jósẹ́fù;
Recommended Reading