Numbers 13:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
láti inú ẹ̀yà Efuraimu, ó rán Hoṣea ọmọ Nuni;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ninu ẹ̀ya Efraimu, Oṣea ọmọ Nuni.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Láti inú ẹ̀yà Éfúráímù, Ósíà ọmọ Núnì;