Numbers 14:1 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Gbogbo àwọn eniyan bẹ̀rẹ̀ sí ké, wọn sì fi gbogbo òru ọjọ́ náà sọkún.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
GBOGBO ijọ si gbé ohùn wọn soke, nwọn si ke: awọn enia na si sọkun li oru na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo ìjọ ènìyàn sì gbóhùn sókè, wọ́n sì sunkún ní òru ọjọ́ náà.