bible
ra
🌐 Language
English
Español
Français
Deutsch
Português
Italiano
Nederlands
Русский
中文
日本語
한국어
العربية
Türkçe
Tiếng Việt
ไทย
Indonesia
All Languages
Home
/
Bible
/
Compare Numbers 14:32
Numbers 14:32 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn ní tiyín, ẹ ó kú ninu aṣálẹ̀ níhìn-ín.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn ẹnyin, okú nyin yio ṣubu li aginjú yi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n ẹ̀yin, òkú yín yóò ṣubú ní ihà yìí.