Numbers 14:37 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
ó bá fi àrùn burúkú pa wọ́n.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ani awọn ọkunrin na ti o mú ìhin buburu ilẹ na wá, nwọn ti ipa àrun kú niwaju OLUWA.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
OLÚWA sì kọlu àwọn ọkùnrin tó mú ìròyìn búburú wá nípa ilẹ̀ náà, àjàkálẹ̀-àrùn sì pa wọ́n níwájú OLÚWA.