Numbers 14:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Mose ati Aaroni bá dojúbolẹ̀ níwájú àwọn eniyan náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni Mose ati Aaroni doju wọn bolẹ niwaju gbogbo ijọ awọn ọmọ Israeli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni Mósè àti Árónì dojú bolẹ̀ níwájú gbogbo ìjọ ọmọ Ísírẹ́lì.