Numbers 15:23 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
àní àwọn òfin tí OLUWA tipasẹ̀ Mose fún yín, láti ọjọ́ tí OLUWA ti fún un ní òfin títí lọ, ní ìrandíran yín;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ani gbogbo eyiti OLUWA ti paṣẹ fun nyin lati ọwọ́ Mose wá, lati ọjọ́ na ti OLUWA ti paṣẹ fun Mose, ati lati isisiyi lọ, ni iran-iran nyin;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èyí ni gbogbo òfin tí OLÚWA fún yín láti ẹnu Mósè láti ọjọ́ tí OLÚWA ti fún yín àti títí dé ìran tó ń bọ̀.