Numbers 16:35 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
OLUWA sì rán iná láti run àwọn aadọtaleerugba (250) ọkunrin tí wọn mú àwo turari wá siwaju Àgọ́ Àjọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iná si jade wá lati ọdọ OLUWA, o si run awọn ãdọtalerugba ọkunrin nì ti nwọn mú turari wá.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Iná sì jáde láti ọ̀dọ̀ OLÚWA ó sì run àádọ́tàlénígba ọkùnrin (250) tí wọ́n mú tùràrí wá.