Numbers 18:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Mo fún ọ ní gbogbo èso àkọ́so tí àwọn ọmọ Israẹli ń mú wá fún mi lọdọọdun, ati òróró tí ó dára jùlọ, ọtí waini tí ó dára jùlọ, ati ọkà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gbogbo oróro daradara, ati gbogbo ọti-waini daradara, ati alikama, akọ́so ninu wọn ti nwọn o mú fun OLUWA wá, iwọ ni mo fi wọn fun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Mo fún ọ ní gbogbo òróró tí ó dára jùlọ àti gbogbo ọtí titun dáradára jùlọ àti ọkà tí wọ́n mú wá fún OLÚWA ní àkọ́so ohun ọ̀gbìn wọn tí wọ́n kórè.